-
Léfítíkù 15:24Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
24 Tí ọkùnrin kan bá bá a sùn, tí ìdọ̀tí nǹkan oṣù rẹ̀ sì kàn án lára,+ ọkùnrin náà máa jẹ́ aláìmọ́ fún ọjọ́ méje, ibùsùn èyíkéyìí tí ọkùnrin náà bá sì dùbúlẹ̀ sí yóò di aláìmọ́.
-
-
Léfítíkù 20:18Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
18 “‘Tí ọkùnrin kan bá sùn ti obìnrin tó ń ṣe nǹkan oṣù, tó sì bá a lò pọ̀, àwọn méjèèjì ti fi ìsun ẹ̀jẹ̀ obìnrin náà hàn síta.+ Ṣe ni kí ẹ pa àwọn méjèèjì, kí ẹ lè mú wọn kúrò láàárín àwọn èèyàn wọn.
-