ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Léfítíkù 16:14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 “Kó mú lára ẹ̀jẹ̀+ akọ màlúù náà, kó fi ìka rẹ̀ wọ́n ọn síwájú ìbòrí náà ní apá ìlà oòrùn, kó sì fi ìka rẹ̀ wọ́n lára ẹ̀jẹ̀ náà lẹ́ẹ̀méje síwájú ìbòrí+ náà.

  • Léfítíkù 16:19
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 19 Kó tún fi ìka rẹ̀ wọ́n lára ẹ̀jẹ̀ náà sára pẹpẹ lẹ́ẹ̀méje, kó lè wẹ̀ ẹ́ mọ́, kó sì sọ ọ́ di mímọ́ kúrò nínú ìwà àìmọ́ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́