ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Diutarónómì 24:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Ọjọ́ yẹn gan-an ni kí o fún un ní owó iṣẹ́ rẹ̀,+ kí oòrùn tó wọ̀, torí pé aláìní ni, owó iṣẹ́ yìí ló sì ń gbé ẹ̀mí* rẹ̀ ró. Àìjẹ́ bẹ́ẹ̀, ó máa fi ẹjọ́ rẹ sun Jèhófà, wàá sì jẹ̀bi ẹ̀ṣẹ̀.+

  • Jeremáyà 22:13
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Ẹni tó ń fi àìṣòdodo kọ́ ilé rẹ̀ ti gbé!

      Tó ń fi àìṣẹ̀tọ́ kọ́ àwọn yàrá òkè rẹ̀,

      Tó ń mú kí ọmọnìkejì rẹ̀ sìn ín láìgba nǹkan kan,

      Tí kò sì fún un ní owó iṣẹ́ rẹ̀;+

  • Jémíìsì 5:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 Wò ó! Owó iṣẹ́ tí ẹ ò san fún àwọn òṣìṣẹ́ tó kórè oko yín ń ké jáde ṣáá, igbe tí àwọn olùkórè ń ké fún ìrànwọ́ sì ti dé etí Jèhófà* Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́