Ẹ́kísódù 30:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Kí Áárónì máa ṣe ètùtù lórí àwọn ìwo rẹ̀ lẹ́ẹ̀kan lọ́dún.+ Kí ó mú lára ẹ̀jẹ̀ ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ ti ètùtù+ láti ṣe ètùtù fún un lẹ́ẹ̀kan lọ́dún jálẹ̀ gbogbo ìran yín. Ohun mímọ́ jù lọ ló jẹ́ sí Jèhófà.”
10 Kí Áárónì máa ṣe ètùtù lórí àwọn ìwo rẹ̀ lẹ́ẹ̀kan lọ́dún.+ Kí ó mú lára ẹ̀jẹ̀ ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ ti ètùtù+ láti ṣe ètùtù fún un lẹ́ẹ̀kan lọ́dún jálẹ̀ gbogbo ìran yín. Ohun mímọ́ jù lọ ló jẹ́ sí Jèhófà.”