-
Diutarónómì 25:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 “O ò gbọ́dọ̀ ní oríṣi òkúta ìwọ̀n méjì nínú àpò rẹ,+ èyí tó tóbi àti èyí tó kéré.
-
-
Diutarónómì 25:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 Ìwọ̀n tó péye tó sì tọ́ àti òṣùwọ̀n tó péye tó sì tọ́ ni kí o máa lò, kí o lè pẹ́ lórí ilẹ̀ tí Jèhófà Ọlọ́run rẹ fẹ́ fún ọ.+
-