Òwe 11:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Òṣùwọ̀n èké* jẹ́ ohun ìríra lójú Jèhófà,Àmọ́ ìwọ̀n* tí ó pé máa ń mú inú rẹ̀ dùn.+