Léfítíkù 18:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Kí ẹ máa pa àwọn àṣẹ mi àti àwọn ìdájọ́ mi mọ́; yóò mú kí ẹnikẹ́ni tó bá ń pa á mọ́ wà láàyè.+ Èmi ni Jèhófà. Diutarónómì 4:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Kí ẹ rí i pé ẹ̀ ń pa wọ́n mọ́,+ torí èyí máa fi hàn pé ẹ jẹ́ ọlọ́gbọ́n+ àti olóye+ lójú àwọn èèyàn tó máa gbọ́ nípa gbogbo ìlànà yìí, wọ́n á sì sọ pé, ‘Ó dájú pé ọlọ́gbọ́n àti olóye ni àwọn èèyàn orílẹ̀-èdè ńlá yìí.’+
5 Kí ẹ máa pa àwọn àṣẹ mi àti àwọn ìdájọ́ mi mọ́; yóò mú kí ẹnikẹ́ni tó bá ń pa á mọ́ wà láàyè.+ Èmi ni Jèhófà.
6 Kí ẹ rí i pé ẹ̀ ń pa wọ́n mọ́,+ torí èyí máa fi hàn pé ẹ jẹ́ ọlọ́gbọ́n+ àti olóye+ lójú àwọn èèyàn tó máa gbọ́ nípa gbogbo ìlànà yìí, wọ́n á sì sọ pé, ‘Ó dájú pé ọlọ́gbọ́n àti olóye ni àwọn èèyàn orílẹ̀-èdè ńlá yìí.’+