Léfítíkù 18:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 “‘O ò gbọ́dọ̀ jẹ́ kí wọ́n fi ìkankan nínú àwọn ọmọ rẹ rúbọ sí* Mólékì.+ O ò gbọ́dọ̀ tipa bẹ́ẹ̀ sọ orúkọ Ọlọ́run rẹ di aláìmọ́.+ Èmi ni Jèhófà. Diutarónómì 18:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ẹnì kankan láàárín yín ò gbọ́dọ̀ sun ọmọkùnrin rẹ̀ tàbí ọmọbìnrin rẹ̀ nínú iná,+ kò gbọ́dọ̀ woṣẹ́,+ kò gbọ́dọ̀ pidán,+ kò gbọ́dọ̀ wá àmì ohun tó fẹ́ ṣẹlẹ̀,+ kò gbọ́dọ̀ di oṣó,+
21 “‘O ò gbọ́dọ̀ jẹ́ kí wọ́n fi ìkankan nínú àwọn ọmọ rẹ rúbọ sí* Mólékì.+ O ò gbọ́dọ̀ tipa bẹ́ẹ̀ sọ orúkọ Ọlọ́run rẹ di aláìmọ́.+ Èmi ni Jèhófà.
10 Ẹnì kankan láàárín yín ò gbọ́dọ̀ sun ọmọkùnrin rẹ̀ tàbí ọmọbìnrin rẹ̀ nínú iná,+ kò gbọ́dọ̀ woṣẹ́,+ kò gbọ́dọ̀ pidán,+ kò gbọ́dọ̀ wá àmì ohun tó fẹ́ ṣẹlẹ̀,+ kò gbọ́dọ̀ di oṣó,+