Léfítíkù 18:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 “‘O ò gbọ́dọ̀ bá ìyàwó bàbá rẹ lò pọ̀.+ Ìyẹn máa dójú ti bàbá rẹ.* Diutarónómì 27:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 “‘Ègún ni fún ẹni tó bá bá ìyàwó bàbá rẹ̀ sùn, torí ó ti dójú ti bàbá rẹ̀.’*+ (Kí gbogbo èèyàn sì sọ pé, ‘Àmín!’)
20 “‘Ègún ni fún ẹni tó bá bá ìyàwó bàbá rẹ̀ sùn, torí ó ti dójú ti bàbá rẹ̀.’*+ (Kí gbogbo èèyàn sì sọ pé, ‘Àmín!’)