-
Léfítíkù 18:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 “‘O ò gbọ́dọ̀ bá ìyàwó ọmọ rẹ lò pọ̀.+ Ìyàwó ọmọ rẹ ni, o ò gbọ́dọ̀ bá a lò pọ̀.
-
-
Léfítíkù 18:29Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
29 Tí ẹnikẹ́ni bá ṣe èyíkéyìí nínú àwọn ohun ìríra yìí, kí ẹ pa gbogbo àwọn* tó bá ń ṣe é, kí ẹ lè mú wọn kúrò láàárín àwọn èèyàn wọn.
-