-
Léfítíkù 18:12, 13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 “‘O ò gbọ́dọ̀ bá arábìnrin bàbá rẹ lò pọ̀. Mọ̀lẹ́bí bàbá rẹ tímọ́tímọ́ ni.+
13 “‘O ò gbọ́dọ̀ bá arábìnrin ìyá rẹ lò pọ̀, torí mọ̀lẹ́bí ìyá rẹ tímọ́tímọ́ ni.
-