-
Léfítíkù 8:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Lẹ́yìn náà, ó mú akọ màlúù ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ wá, Áárónì àti àwọn ọmọ rẹ̀ sì gbé ọwọ́ lé orí akọ màlúù ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀+ náà.
-
-
Léfítíkù 8:17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
17 Ó wá fi iná sun ohun tó ṣẹ́ kù lára akọ màlúù náà, awọ rẹ̀, ẹran rẹ̀ àti ìgbẹ́ rẹ̀ ní ẹ̀yìn ibùdó+ bí Jèhófà ṣe pa á láṣẹ fún un.
-