Léfítíkù 19:27, 28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 “‘Ẹ ò gbọ́dọ̀ fá* irun ẹ̀gbẹ́ orí yín tàbí kí ẹ ba eteetí irùngbọ̀n yín jẹ́.+ 28 “‘Ẹ ò gbọ́dọ̀ kọ ara yín lábẹ torí ẹni tó kú,*+ ẹ ò sì gbọ́dọ̀ fín àmì sí ara yín. Èmi ni Jèhófà.
27 “‘Ẹ ò gbọ́dọ̀ fá* irun ẹ̀gbẹ́ orí yín tàbí kí ẹ ba eteetí irùngbọ̀n yín jẹ́.+ 28 “‘Ẹ ò gbọ́dọ̀ kọ ara yín lábẹ torí ẹni tó kú,*+ ẹ ò sì gbọ́dọ̀ fín àmì sí ara yín. Èmi ni Jèhófà.