-
Ẹ́kísódù 29:44Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
44 Màá sọ àgọ́ ìpàdé àti pẹpẹ di mímọ́, màá sì sọ Áárónì àti àwọn ọmọ rẹ̀+ di mímọ́, kí wọ́n lè di àlùfáà mi.