Léfítíkù 19:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 “‘Má ba ọmọbìnrin rẹ jẹ́ nípa sísọ ọ́ di aṣẹ́wó,+ kí ilẹ̀ náà má bàa ṣiṣẹ́ aṣẹ́wó, kí ìwà ìbàjẹ́+ sì kún ibẹ̀.
29 “‘Má ba ọmọbìnrin rẹ jẹ́ nípa sísọ ọ́ di aṣẹ́wó,+ kí ilẹ̀ náà má bàa ṣiṣẹ́ aṣẹ́wó, kí ìwà ìbàjẹ́+ sì kún ibẹ̀.