Diutarónómì 24:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 “Tí ọkùnrin kan bá fẹ́ obìnrin kan, àmọ́ tí obìnrin náà ò tẹ́ ẹ lọ́rùn torí ó rí ohun kan tí kò dáa nípa rẹ̀, kó kọ ìwé ẹ̀rí ìkọ̀sílẹ̀ fún un,+ kó fi lé e lọ́wọ́, kó sì ní kó kúrò ní ilé òun.+ Ìsíkíẹ́lì 44:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Wọn ò gbọ́dọ̀ fẹ́ opó tàbí obìnrin tí ọkọ rẹ̀ kọ̀ sílẹ̀;+ àmọ́ wọ́n lè fẹ́ ọmọ Ísírẹ́lì tó jẹ́ wúńdíá tàbí ìyàwó àlùfáà tó ti di opó.’+
24 “Tí ọkùnrin kan bá fẹ́ obìnrin kan, àmọ́ tí obìnrin náà ò tẹ́ ẹ lọ́rùn torí ó rí ohun kan tí kò dáa nípa rẹ̀, kó kọ ìwé ẹ̀rí ìkọ̀sílẹ̀ fún un,+ kó fi lé e lọ́wọ́, kó sì ní kó kúrò ní ilé òun.+
22 Wọn ò gbọ́dọ̀ fẹ́ opó tàbí obìnrin tí ọkọ rẹ̀ kọ̀ sílẹ̀;+ àmọ́ wọ́n lè fẹ́ ọmọ Ísírẹ́lì tó jẹ́ wúńdíá tàbí ìyàwó àlùfáà tó ti di opó.’+