Ẹ́kísódù 28:41 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 41 Kí o wọ aṣọ fún Áárónì ẹ̀gbọ́n rẹ àti àwọn ọmọ rẹ̀, kí o fòróró yàn wọ́n,+ kí o fiṣẹ́ lé wọn lọ́wọ́,*+ kí o sì sọ wọ́n di mímọ́, wọ́n á sì di àlùfáà mi.
41 Kí o wọ aṣọ fún Áárónì ẹ̀gbọ́n rẹ àti àwọn ọmọ rẹ̀, kí o fòróró yàn wọ́n,+ kí o fiṣẹ́ lé wọn lọ́wọ́,*+ kí o sì sọ wọ́n di mímọ́, wọ́n á sì di àlùfáà mi.