Léfítíkù 20:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 “‘Tí ọkùnrin kan bá bá ìyà àti ọmọ lò pọ̀, ìwà àìnítìjú* ló hù.+ Ṣe ni kí ẹ fi iná sun+ òun pẹ̀lú wọn, kí ìwà àìnítìjú má bàa gbilẹ̀ láàárín yín.
14 “‘Tí ọkùnrin kan bá bá ìyà àti ọmọ lò pọ̀, ìwà àìnítìjú* ló hù.+ Ṣe ni kí ẹ fi iná sun+ òun pẹ̀lú wọn, kí ìwà àìnítìjú má bàa gbilẹ̀ láàárín yín.