-
Léfítíkù 10:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Mósè wá sọ fún Áárónì àti àwọn ọmọ rẹ̀ yòókù, Élíásárì àti Ítámárì, pé: “Ẹ má fi irun orí yín sílẹ̀ láìtọ́jú, ẹ ò sì gbọ́dọ̀ ya aṣọ yín,+ kí ẹ má bàa kú, kí Ọlọ́run má bàa bínú sí gbogbo àpéjọ yìí. Àwọn arákùnrin yín ní gbogbo ilé Ísírẹ́lì máa sunkún torí àwọn tí Jèhófà fi iná pa.
-