Ìsíkíẹ́lì 44:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Wọn ò gbọ́dọ̀ fẹ́ opó tàbí obìnrin tí ọkọ rẹ̀ kọ̀ sílẹ̀;+ àmọ́ wọ́n lè fẹ́ ọmọ Ísírẹ́lì tó jẹ́ wúńdíá tàbí ìyàwó àlùfáà tó ti di opó.’+
22 Wọn ò gbọ́dọ̀ fẹ́ opó tàbí obìnrin tí ọkọ rẹ̀ kọ̀ sílẹ̀;+ àmọ́ wọ́n lè fẹ́ ọmọ Ísírẹ́lì tó jẹ́ wúńdíá tàbí ìyàwó àlùfáà tó ti di opó.’+