Ẹ́sírà 9:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Wọ́n ti fi lára àwọn ọmọbìnrin wọn ṣe aya, wọ́n sì tún fẹ́ wọn fún àwọn ọmọkùnrin wọn.+ Ní báyìí, àwọn tí wọ́n jẹ́ ọmọ* mímọ́+ ti dara pọ̀ mọ́ àwọn èèyàn àwọn ilẹ̀ tó yí wọn ká.+ Àwọn olórí àti àwọn alábòójútó sì ni òléwájú nínú ìwà àìṣòótọ́ yìí.”
2 Wọ́n ti fi lára àwọn ọmọbìnrin wọn ṣe aya, wọ́n sì tún fẹ́ wọn fún àwọn ọmọkùnrin wọn.+ Ní báyìí, àwọn tí wọ́n jẹ́ ọmọ* mímọ́+ ti dara pọ̀ mọ́ àwọn èèyàn àwọn ilẹ̀ tó yí wọn ká.+ Àwọn olórí àti àwọn alábòójútó sì ni òléwájú nínú ìwà àìṣòótọ́ yìí.”