-
Diutarónómì 23:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
23 “Ọkùnrin èyíkéyìí tí wọ́n bá tẹ̀ lọ́dàá, tí wọ́n fọ́ kórópọ̀n rẹ̀ tàbí tí wọ́n gé ẹ̀yà ìbímọ rẹ̀ kúrò kò gbọ́dọ̀ wá sínú ìjọ Jèhófà.+
-