Ẹ́kísódù 30:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Kí o gbé e síwájú aṣọ ìdábùú tó wà nítòsí àpótí Ẹ̀rí,+ níwájú ìbòrí tó wà lórí Ẹ̀rí, níbi tí màá ti pàdé rẹ.+
6 Kí o gbé e síwájú aṣọ ìdábùú tó wà nítòsí àpótí Ẹ̀rí,+ níwájú ìbòrí tó wà lórí Ẹ̀rí, níbi tí màá ti pàdé rẹ.+