ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 28:38
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 38 Yóò wà ní iwájú orí Áárónì, kí Áárónì sì máa ru ẹ̀bi ẹni tó bá ṣe ohun tí kò tọ́ sí àwọn ohun mímọ́,+ èyí tí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì yà sí mímọ́ nígbà tí wọ́n fi ṣe ẹ̀bùn mímọ́. Kò gbọ́dọ̀ kúrò níwájú orí rẹ̀, kí wọ́n lè rí ojú rere Jèhófà.

  • Nọ́ńbà 18:32
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 32 Ẹ ò ní dẹ́ṣẹ̀ tí ẹ bá ṣe bẹ́ẹ̀, tó bá ṣáà ti jẹ́ èyí tó dáa jù lẹ́ fi ṣe ọrẹ, ẹ ò sì gbọ́dọ̀ sọ àwọn ohun mímọ́ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì di aláìmọ́, àìjẹ́ bẹ́ẹ̀, ẹ máa kú.’”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́