Léfítíkù 7:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 “‘Àmọ́ tí ẹnikẹ́ni* tó jẹ́ aláìmọ́ bá jẹ ẹran ẹbọ ìrẹ́pọ̀, tó jẹ́ ti Jèhófà, kí ẹ pa ẹni* náà, kí ẹ lè mú un kúrò láàárín àwọn èèyàn rẹ̀.+
20 “‘Àmọ́ tí ẹnikẹ́ni* tó jẹ́ aláìmọ́ bá jẹ ẹran ẹbọ ìrẹ́pọ̀, tó jẹ́ ti Jèhófà, kí ẹ pa ẹni* náà, kí ẹ lè mú un kúrò láàárín àwọn èèyàn rẹ̀.+