Ẹ́kísódù 29:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 Kí wọ́n jẹ àwọn nǹkan tí wọ́n fi ṣe ètùtù láti sọ wọ́n di àlùfáà,* kí wọ́n sì di mímọ́. Àmọ́ ẹni tí kò lẹ́tọ̀ọ́ sí i* ò gbọ́dọ̀ jẹ ẹ́, torí ohun mímọ́ ni.+
33 Kí wọ́n jẹ àwọn nǹkan tí wọ́n fi ṣe ètùtù láti sọ wọ́n di àlùfáà,* kí wọ́n sì di mímọ́. Àmọ́ ẹni tí kò lẹ́tọ̀ọ́ sí i* ò gbọ́dọ̀ jẹ ẹ́, torí ohun mímọ́ ni.+