-
Nọ́ńbà 18:32Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
32 Ẹ ò ní dẹ́ṣẹ̀ tí ẹ bá ṣe bẹ́ẹ̀, tó bá ṣáà ti jẹ́ èyí tó dáa jù lẹ́ fi ṣe ọrẹ, ẹ ò sì gbọ́dọ̀ sọ àwọn ohun mímọ́ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì di aláìmọ́, àìjẹ́ bẹ́ẹ̀, ẹ máa kú.’”+
-