-
Diutarónómì 22:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 “Tí o bá ṣàdédé rí ìtẹ́ ẹyẹ kan lójú ọ̀nà, tí àwọn ọmọ rẹ̀ tàbí àwọn ẹyin rẹ̀ wà nínú ìtẹ́ náà, ì báà jẹ́ lórí igi tàbí lórí ilẹ̀, tí àwọn ọmọ náà wà lábẹ́ ìyá wọn tàbí tó sàba lórí àwọn ẹyin náà, o ò gbọ́dọ̀ mú ìyá náà pẹ̀lú àwọn ọmọ rẹ̀.+
-