Léfítíkù 18:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 “‘O ò gbọ́dọ̀ jẹ́ kí wọ́n fi ìkankan nínú àwọn ọmọ rẹ rúbọ sí* Mólékì.+ O ò gbọ́dọ̀ tipa bẹ́ẹ̀ sọ orúkọ Ọlọ́run rẹ di aláìmọ́.+ Èmi ni Jèhófà. Léfítíkù 19:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Ẹ ò gbọ́dọ̀ fi orúkọ mi búra èké,+ kí ẹ má bàa sọ orúkọ Ọlọ́run yín di aláìmọ́. Èmi ni Jèhófà.
21 “‘O ò gbọ́dọ̀ jẹ́ kí wọ́n fi ìkankan nínú àwọn ọmọ rẹ rúbọ sí* Mólékì.+ O ò gbọ́dọ̀ tipa bẹ́ẹ̀ sọ orúkọ Ọlọ́run rẹ di aláìmọ́.+ Èmi ni Jèhófà.