1 Kọ́ríńtì 15:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Àmọ́ ní báyìí, a ti gbé Kristi dìde kúrò nínú ikú, àkọ́so nínú àwọn tó ti sùn nínú ikú.+ 1 Kọ́ríńtì 15:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Àmọ́ kálukú wà ní àyè rẹ̀: Kristi àkọ́so,+ lẹ́yìn náà àwọn tó jẹ́ ti Kristi nígbà tó bá wà níhìn-ín.+
23 Àmọ́ kálukú wà ní àyè rẹ̀: Kristi àkọ́so,+ lẹ́yìn náà àwọn tó jẹ́ ti Kristi nígbà tó bá wà níhìn-ín.+