-
Léfítíkù 7:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 “‘Òfin ẹbọ ìrẹ́pọ̀+ tí ẹnì kan bá mú wá fún Jèhófà nìyí:
-
-
Léfítíkù 7:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Kó mú ọrẹ rẹ̀ wá pẹ̀lú búrẹ́dì tí wọ́n fi ìwúkàrà sí tó rí bí òrùka, kó sì mú ẹbọ ìdúpẹ́ ti ẹbọ ìrẹ́pọ̀ rẹ̀ wá.
-