Ẹ́kísódù 18:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Kí wọ́n máa dá ẹjọ́ tí àwọn èèyàn náà bá gbé wá.* Kí wọ́n máa gbé gbogbo ẹjọ́ tó bá ṣòroó dá wá sọ́dọ̀ rẹ,+ àmọ́ kí wọ́n máa dá àwọn ẹjọ́ tí kò tó nǹkan. Jẹ́ kí wọ́n bá ọ gbé lára ẹrù yìí kí nǹkan lè rọrùn fún ọ.+
22 Kí wọ́n máa dá ẹjọ́ tí àwọn èèyàn náà bá gbé wá.* Kí wọ́n máa gbé gbogbo ẹjọ́ tó bá ṣòroó dá wá sọ́dọ̀ rẹ,+ àmọ́ kí wọ́n máa dá àwọn ẹjọ́ tí kò tó nǹkan. Jẹ́ kí wọ́n bá ọ gbé lára ẹrù yìí kí nǹkan lè rọrùn fún ọ.+