Ẹ́kísódù 21:23, 24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Àmọ́ tó bá la ẹ̀mí lọ, kí o fi ẹ̀mí dípò ẹ̀mí,*+ 24 ojú dípò ojú, eyín dípò eyín, ọwọ́ dípò ọwọ́, ẹsẹ̀ dípò ẹsẹ̀,+
23 Àmọ́ tó bá la ẹ̀mí lọ, kí o fi ẹ̀mí dípò ẹ̀mí,*+ 24 ojú dípò ojú, eyín dípò eyín, ọwọ́ dípò ọwọ́, ẹsẹ̀ dípò ẹsẹ̀,+