-
Nọ́ńbà 15:33Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
33 Àwọn tó rí i níbi tó ti ń ṣa igi wá mú un lọ sọ́dọ̀ Mósè àti Áárónì àti gbogbo àpéjọ náà.
-
-
Nọ́ńbà 15:36Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
36 Torí náà, gbogbo àpéjọ náà mú un lọ sí ẹ̀yìn ibùdó, wọ́n sì sọ ọ́ ní òkúta pa, bí Jèhófà ṣe pa á láṣẹ fún Mósè.
-