-
Léfítíkù 25:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Ẹ ò gbọ́dọ̀ kórè ohun tó hù fúnra rẹ̀ látinú ọkà tó ṣẹ́ kù lẹ́yìn tí ẹ kórè, ẹ má sì kó àwọn èso àjàrà yín tí ẹ ò tíì rẹ́wọ́ rẹ̀ jọ. Ẹ jẹ́ kí ilẹ̀ náà sinmi pátápátá fún ọdún kan.
-