-
Ẹ́kísódù 23:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Àmọ́ ní ọdún keje, kí o fi ilẹ̀ náà sílẹ̀ láìro, má fi dá oko. Àwọn tó jẹ́ aláìní nínú àwọn èèyàn rẹ yóò jẹ nínú rẹ̀, àwọn ẹran inú igbó yóò sì jẹ ohun tí wọ́n bá ṣẹ́ kù. Ohun tí o máa ṣe sí ọgbà àjàrà rẹ àti àwọn igi ólífì rẹ nìyẹn.
-
-
Léfítíkù 25:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Àmọ́ ẹ lè jẹ ohun tó bá hù ní ilẹ̀ náà nígbà sábáàtì rẹ̀; ẹ̀yin, ẹrúkùnrin àti ẹrúbìnrin yín, àwọn alágbàṣe yín àti àwọn àjèjì tó ń gbé láàárín yín lè jẹ ẹ́,
-