1 Àwọn Ọba 21:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Àmọ́ Nábótì sọ fún Áhábù pé: “Jèhófà ò ní fẹ́ gbọ́ rárá pé mo fi ogún àwọn baba ńlá mi+ fún ọ.”