Léfítíkù 25:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 “‘Àmọ́ tí kò bá lágbára láti gbà á pa dà lọ́wọ́ ẹni náà, ohun tó tà máa wà lọ́wọ́ ẹni tó rà á títí di ọdún Júbílì;+ yóò pa dà sọ́wọ́ rẹ̀ nígbà Júbílì, ohun ìní rẹ̀ á sì pa dà di tirẹ̀.+
28 “‘Àmọ́ tí kò bá lágbára láti gbà á pa dà lọ́wọ́ ẹni náà, ohun tó tà máa wà lọ́wọ́ ẹni tó rà á títí di ọdún Júbílì;+ yóò pa dà sọ́wọ́ rẹ̀ nígbà Júbílì, ohun ìní rẹ̀ á sì pa dà di tirẹ̀.+