-
Léfítíkù 25:26, 27Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
26 Tí ẹnì kan ò bá ní olùtúnrà, àmọ́ tó ti wá lọ́rọ̀, tó sì lágbára láti tún ohun ìní náà rà, 27 kó ṣírò iye rẹ̀ láti ọdún tó ti tà á, kó sì dá owó tó ṣẹ́ kù pa dà fún ẹni tó tà á fún. Ohun ìní rẹ̀ á wá pa dà di tirẹ̀.+
-