Léfítíkù 26:36 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 36 “‘Ní ti àwọn tó bá yè é,+ màá fi ìbẹ̀rù kún ọkàn wọn ní ilẹ̀ àwọn ọ̀tá wọn; ìró ewé tí atẹ́gùn ń fẹ́ máa lé wọn sá, wọ́n á fẹsẹ̀ fẹ bí ẹni ń sá fún idà, wọ́n á sì ṣubú láìsí ẹni tó ń lé wọn.+
36 “‘Ní ti àwọn tó bá yè é,+ màá fi ìbẹ̀rù kún ọkàn wọn ní ilẹ̀ àwọn ọ̀tá wọn; ìró ewé tí atẹ́gùn ń fẹ́ máa lé wọn sá, wọ́n á fẹsẹ̀ fẹ bí ẹni ń sá fún idà, wọ́n á sì ṣubú láìsí ẹni tó ń lé wọn.+