Jeremáyà 9:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Màá tú wọn ká sáàárín àwọn orílẹ̀-èdè tí àwọn pẹ̀lú àwọn baba wọn kò mọ̀,+ màá sì rán idà sí wọn títí màá fi pa wọ́n run.’+ Ìsíkíẹ́lì 12:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Gbogbo àwọn tó yí i ká, àwọn olùrànlọ́wọ́ rẹ̀ àti àwọn ọmọ ogun rẹ̀ ni màá fọ́n káàkiri;+ èmi yóò sì fa idà yọ kí n lè lé wọn bá.+
16 Màá tú wọn ká sáàárín àwọn orílẹ̀-èdè tí àwọn pẹ̀lú àwọn baba wọn kò mọ̀,+ màá sì rán idà sí wọn títí màá fi pa wọ́n run.’+
14 Gbogbo àwọn tó yí i ká, àwọn olùrànlọ́wọ́ rẹ̀ àti àwọn ọmọ ogun rẹ̀ ni màá fọ́n káàkiri;+ èmi yóò sì fa idà yọ kí n lè lé wọn bá.+