-
Lúùkù 21:2-4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Ó wá rí opó aláìní kan tó fi ẹyọ owó kéékèèké méjì tí ìníyelórí rẹ̀ kéré gan-an* síbẹ̀,+ 3 ó sì sọ pé: “Lóòótọ́ ni mo sọ fún yín pé ohun tí opó aláìní yìí fi sílẹ̀ ju ti gbogbo wọn lọ.+ 4 Torí gbogbo àwọn yìí fi ẹ̀bùn sílẹ̀ látinú àjẹṣẹ́kù wọn, àmọ́ òun, láìka pé kò ní lọ́wọ́,* ó fi gbogbo ohun tó ní láti gbé ẹ̀mí rẹ̀ ró síbẹ̀.”+
-