-
Léfítíkù 27:19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
19 Àmọ́ tí ẹni tó ya ilẹ̀ náà sí mímọ́ bá tiẹ̀ fẹ́ rà á pa dà, ó gbọ́dọ̀ fi ìdá márùn-ún iye tí wọ́n dá lé e kún un, yóò sì di tirẹ̀.
-