Ẹ́kísódù 22:30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 Ohun tí wàá ṣe sí akọ màlúù àti àgùntàn rẹ nìyí:+ Kí ó wà pẹ̀lú ìyá rẹ̀ fún ọjọ́ méje. Tó bá di ọjọ́ kẹjọ, kí o mú un wá fún mi.+ Diutarónómì 15:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 “Gbogbo àkọ́bí tó jẹ́ akọ nínú ọ̀wọ́ ẹran rẹ àti nínú agbo ẹran rẹ ni kí o yà sọ́tọ̀ fún Jèhófà Ọlọ́run rẹ.+ O ò gbọ́dọ̀ fi àkọ́bí nínú ọ̀wọ́ ẹran* rẹ ṣe iṣẹ́ kankan, o ò sì gbọ́dọ̀ rẹ́ irun àkọ́bí nínú agbo ẹran rẹ.
30 Ohun tí wàá ṣe sí akọ màlúù àti àgùntàn rẹ nìyí:+ Kí ó wà pẹ̀lú ìyá rẹ̀ fún ọjọ́ méje. Tó bá di ọjọ́ kẹjọ, kí o mú un wá fún mi.+
19 “Gbogbo àkọ́bí tó jẹ́ akọ nínú ọ̀wọ́ ẹran rẹ àti nínú agbo ẹran rẹ ni kí o yà sọ́tọ̀ fún Jèhófà Ọlọ́run rẹ.+ O ò gbọ́dọ̀ fi àkọ́bí nínú ọ̀wọ́ ẹran* rẹ ṣe iṣẹ́ kankan, o ò sì gbọ́dọ̀ rẹ́ irun àkọ́bí nínú agbo ẹran rẹ.