Nọ́ńbà 5:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ó* gbọ́dọ̀ jẹ́wọ́+ ẹ̀ṣẹ̀ tó* dá, kó san ohun tó jẹ̀bi rẹ̀ pa dà ní ẹ̀kúnrẹ́rẹ́, kó sì fi ìdá márùn-ún rẹ̀+ kún un; kó fún ẹni tó ṣe àìdáa sí. Sáàmù 32:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Níkẹyìn, mo jẹ́wọ́ ẹ̀ṣẹ̀ mi fún ọ;Mi ò bo àṣìṣe mi mọ́lẹ̀.+ Mo sọ pé: “Màá jẹ́wọ́ àwọn ẹ̀ṣẹ̀ mi fún Jèhófà.”+ O sì dárí àṣìṣe àti ẹ̀ṣẹ̀ mi jì mí.+ (Sélà) Òwe 28:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ẹni tó bá ń bo àwọn ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀ mọ́lẹ̀ kò ní ṣàṣeyọrí,+Àmọ́ ẹni tó bá jẹ́wọ́, tó sì fi wọ́n sílẹ̀ la ó fi àánú hàn sí.+ 1 Jòhánù 1:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Tí a bá jẹ́wọ́ àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wa, ó máa dárí jì wá, ó sì máa wẹ̀ wá mọ́ kúrò nínú gbogbo àìṣòdodo torí olóòótọ́ àti olódodo ni.+
7 Ó* gbọ́dọ̀ jẹ́wọ́+ ẹ̀ṣẹ̀ tó* dá, kó san ohun tó jẹ̀bi rẹ̀ pa dà ní ẹ̀kúnrẹ́rẹ́, kó sì fi ìdá márùn-ún rẹ̀+ kún un; kó fún ẹni tó ṣe àìdáa sí.
5 Níkẹyìn, mo jẹ́wọ́ ẹ̀ṣẹ̀ mi fún ọ;Mi ò bo àṣìṣe mi mọ́lẹ̀.+ Mo sọ pé: “Màá jẹ́wọ́ àwọn ẹ̀ṣẹ̀ mi fún Jèhófà.”+ O sì dárí àṣìṣe àti ẹ̀ṣẹ̀ mi jì mí.+ (Sélà)
13 Ẹni tó bá ń bo àwọn ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀ mọ́lẹ̀ kò ní ṣàṣeyọrí,+Àmọ́ ẹni tó bá jẹ́wọ́, tó sì fi wọ́n sílẹ̀ la ó fi àánú hàn sí.+
9 Tí a bá jẹ́wọ́ àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wa, ó máa dárí jì wá, ó sì máa wẹ̀ wá mọ́ kúrò nínú gbogbo àìṣòdodo torí olóòótọ́ àti olódodo ni.+