-
Léfítíkù 27:9, 10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 “‘Tó bá jẹ́ ẹran tó bójú mu láti fi ṣe ọrẹ fún Jèhófà ló jẹ́jẹ̀ẹ́ pé òun máa mú wá, ohunkóhun tó bá fún Jèhófà yóò di mímọ́. 10 Kó má pààrọ̀ rẹ̀, kó má sì fi èyí tó dáa rọ́pò èyí tí kò dáa tàbí kó fi èyí tí kò dáa rọ́pò èyí tó dáa. Àmọ́ tó bá fi ẹran pààrọ̀ ẹran, ẹran tó pààrọ̀ àti èyí tó fi pààrọ̀ yóò di ohun mímọ́.
-