Lúùkù 2:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Wọ́n sì rúbọ bí Òfin Jèhófà* ṣe sọ: “ẹyẹ oriri méjì tàbí ọmọ ẹyẹlé méjì.”+