-
Nọ́ńbà 3:45Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
45 “Mú àwọn ọmọ Léfì dípò gbogbo àkọ́bí nínú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, kí o sì mú ẹran ọ̀sìn àwọn ọmọ Léfì dípò àwọn ẹran ọ̀sìn wọn, àwọn ọmọ Léfì yóò sì di tèmi. Èmi ni Jèhófà.
-