Jẹ́nẹ́sísì 46:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Àwọn ọmọ Léfì+ ni Gẹ́ṣónì, Kóhátì àti Mérárì.+ Ẹ́kísódù 6:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Orúkọ àwọn ọmọ Léfì+ nìyí, gẹ́gẹ́ bí ìlà ìdílé wọn: Gẹ́ṣónì, Kóhátì àti Mérárì.+ Ọjọ́ ayé Léfì jẹ́ ọdún mẹ́tàdínlógóje (137).
16 Orúkọ àwọn ọmọ Léfì+ nìyí, gẹ́gẹ́ bí ìlà ìdílé wọn: Gẹ́ṣónì, Kóhátì àti Mérárì.+ Ọjọ́ ayé Léfì jẹ́ ọdún mẹ́tàdínlógóje (137).