-
Nọ́ńbà 3:39Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
39 Gbogbo ọmọ Léfì tó jẹ́ ọkùnrin láti ọmọ oṣù kan sókè, tí Mósè àti Áárónì forúkọ wọn sílẹ̀ ní ìdílé-ìdílé, bí Jèhófà ṣe pa á láṣẹ jẹ́ ẹgbẹ̀rún méjìlélógún (22,000).
-